AToZ: Software Testing and Automation In Yoruba Language
AToZ: Software Testing and Automation In Yoruba Language, available at $19.99, has an average rating of 4.55, with 71 lectures, based on 32 reviews, and has 84 subscribers.
You will learn about Ninu ẹkọ yi, a o kọ lati Setup Working Environment fun Software Testing ati Automation A o kọ In and Out Functional Testing fun Web Application, Mobile Apps Ati Desktop Applications A o kọ lati lo SQL Server Management Studio (SSMS) lati Query SQL Server Database A o kọ lati lo Selenium WebDriver fun Automating Web Applications A o kọ lati lo Java Eclipse Integration Development Environment (IDE) pẹlu Selenium WebDriver A o kọ lati lo Exploratory Testing A o kọ lati lo SQL Server Integration Services (SSIS) lati Upload Data sinu SQL Server Database A o kọ nipa Basic Microsoft Excel (Spreadsheet) ati Microsoft Word (Document) Object fun Creating Simple Dashboard A o kọ bi a o ṣe Migrate Microsoft Access Database lọ si MSSQL Server Database A o kọ Data Migration Testing A o kọ lati le Report Bugs Tabi Defects A o kọ End To End Testing A o kọ Regression Testing A o kọ lati lo MSSQL Server Database fun Extract Transform Load (ETL Testing) ati Database Testing A o kọ lati le Create Test Script Template pẹlu Microsoft Excel fun Desktop, Mobile ati Web Applications A o kọ lati Gain Working Experience As a Primary Tester at bẹ bẹ lọ This course is ideal for individuals who are Ẹkọ yi wa fu ẹni ti o ba fẹ di :- or Test Analyst or Software Quality Assurance Tester or Mobile Tester or Web Application Tester or Software Test Automation Engineer or Ati Ẹni ti o ba fẹ revise lo ri Testing Skills It is particularly useful for Ẹkọ yi wa fu ẹni ti o ba fẹ di :- or Test Analyst or Software Quality Assurance Tester or Mobile Tester or Web Application Tester or Software Test Automation Engineer or Ati Ẹni ti o ba fẹ revise lo ri Testing Skills.
Enroll now: AToZ: Software Testing and Automation In Yoruba Language
Summary
Title: AToZ: Software Testing and Automation In Yoruba Language
Price: $19.99
Average Rating: 4.55
Number of Lectures: 71
Number of Published Lectures: 71
Number of Curriculum Items: 71
Number of Published Curriculum Objects: 71
Original Price: £99.99
Quality Status: approved
Status: Live
What You Will Learn
- Ninu ẹkọ yi, a o kọ lati Setup Working Environment fun Software Testing ati Automation
- A o kọ In and Out Functional Testing fun Web Application, Mobile Apps Ati Desktop Applications
- A o kọ lati lo SQL Server Management Studio (SSMS) lati Query SQL Server Database
- A o kọ lati lo Selenium WebDriver fun Automating Web Applications
- A o kọ lati lo Java Eclipse Integration Development Environment (IDE) pẹlu Selenium WebDriver
- A o kọ lati lo Exploratory Testing
- A o kọ lati lo SQL Server Integration Services (SSIS) lati Upload Data sinu SQL Server Database
- A o kọ nipa Basic Microsoft Excel (Spreadsheet) ati Microsoft Word (Document) Object fun Creating Simple Dashboard
- A o kọ bi a o ṣe Migrate Microsoft Access Database lọ si MSSQL Server Database
- A o kọ Data Migration Testing
- A o kọ lati le Report Bugs Tabi Defects
- A o kọ End To End Testing
- A o kọ Regression Testing
- A o kọ lati lo MSSQL Server Database fun Extract Transform Load (ETL Testing) ati Database Testing
- A o kọ lati le Create Test Script Template pẹlu Microsoft Excel fun Desktop, Mobile ati Web Applications
- A o kọ lati Gain Working Experience As a Primary Tester at bẹ bẹ lọ
Who Should Attend
- Ẹkọ yi wa fu ẹni ti o ba fẹ di :-
- Test Analyst
- Software Quality Assurance Tester
- Mobile Tester
- Web Application Tester
- Software Test Automation Engineer
- Ati Ẹni ti o ba fẹ revise lo ri Testing Skills
Target Audiences
- Ẹkọ yi wa fu ẹni ti o ba fẹ di :-
- Test Analyst
- Software Quality Assurance Tester
- Mobile Tester
- Web Application Tester
- Software Test Automation Engineer
- Ati Ẹni ti o ba fẹ revise lo ri Testing Skills
Ẹ kabọ si course ton jẹ Kọ Software Testing Ati Automation Pẹlu (Real-Life Projects).
Lakọkọ ẹ jẹ ki a ni lo kan wipe course yi ma jẹ hands-on training tutorial (itumo nin pe 90% practical ati 10% theories). Kiko ni mi mo.
Ninu Course yi ẹ ma learn step by step Manual and Automation Software Testing (Functional) ti a ma lo WinAutomation, Selenium WebDriver 3 ati iMacros browser addons fun automating the Functional part of Web Applications pẹlu over 20+ real life projects.
Software Testing Manual ati Automation jẹ most important skills lati le test front-end ati backend Web Application, Desktop Applications ati Mobile Apps. Paapa ju li lo iMacros ati Selenium WebDriver 3 fun GUI automation, Software Testing Automation je popular larin large community.
Course yi structured si ọ nọ pupọọ:
Awọn ẹkọ yi pisi video screencast ati guide, Homework wa ni be ti a ma se, Ninu ẹkọ yi, a o kọ lati Setup Working Environment fun Software Testing ati Automation, A o kọ In and Out Functional Testing fun Web Application, Mobile Apps Ati Desktop Applications, A o kọ lati lo SQL Server Management Studio (SSMS) lati Query SQL Server Database, A o kọ lati lo Selenium WebDriver fun Automating Web Applications, A o kọ lati lo Java Eclipse Integration Development Environment (IDE) pẹlu Selenium WebDriver, A o kọ lati lo Extract Transform Load (ETL Testing), MS Excel, Notepad++, Test Script, ati Java Code Templates, A o kọ lati lo SQL Server Integration Services (SSIS) lati Upload Data sinu SQL Server Database, A o kọ nipa Basic Microsoft Excel (Spreadsheet) ati Microsoft Word (Document) Object fun Creating Simple Dashboard, A o kọ bi a o ṣe Migrate Microsoft Access Database lọ si MSSQL Server Database, A o kọ Data Migration Testing, A o kọ lati le Report Bugs tabi Defects ati bẹ bẹ lọ.
This course is backed by udemy’s 30-day money back guarantee. If you are not satisfied for any reason, you will get the money back. In addition to that you will keep all the code files of the course as a thank you for trying out the course !!!
Course Curriculum
Chapter 1: Section 1: E je ki a bere
Lecture 1: E̩ jẹ ki a bẹrẹ – Introduction
Lecture 2: Nipa Software Testing – A Brief Overview of Software Testing
Lecture 3: Nipa Olukọ ati Ẹkọ – Course Overview
Chapter 2: Section 2: O ṣe Setup Working Environment fun Software Testing ati Automation
Lecture 1: Bi a o ṣe Download ati Install Eclipse IDE – Installation of Eclipse IDE
Lecture 2: Bi a o ṣe Download Selenium WebDriver ati Integrate sinu Eclipse IDE
Lecture 3: Bi a o ṣe Install Microsoft SQL Server Database Engine pẹlu Management Studio
Lecture 4: Bi a o ṣe Install Microsoft SQL Server Data Tools – SSDT Business Intelligence
Lecture 5: Bi a o ṣe Install Browser Addons fun Firefox, Chrome at Internet Explorer
Lecture 6: Bi a o ṣe Install WinAutomation
Lecture 7: Bi a o ṣe Install Notepad ++
Lecture 8: Bi a o ṣe Install MS Access 2013 Access Runtime
Lecture 9: Bi a o ṣe Install Microsoft SQL Server Migration Access 7.3
Lecture 10: Bi a o ṣe Install NoxPlayer tabi Bluestacks fun Mobile Testing (*.apk)
Lecture 11: Skills fun Software Tester tabi QA Tester
Chapter 3: Section 3: A o kọ Basic Microsoft Excel fun Software Tabi QA tester
Lecture 1: Kinni idi fun Excel?
Lecture 2: A o kọ nipa COUNT
Lecture 3: A o kọ nipa COUNTA
Lecture 4: A o kọ nipa COUNTBLANK
Lecture 5: A o kọ nipa COUNTIF
Lecture 6: A o kọ nipa IF
Lecture 7: A o kọ nipa IF OR
Lecture 8: A o kọ nipa IF AND
Lecture 9: A o kọ nipa NESTED IF
Lecture 10: A o kọ nipa MAX
Lecture 11: A o kọ nipa VLOOKUP
Lecture 12: A o kọ nipa CONDITIONAL FORMATING
Lecture 13: A o kọ nipa Simple CHART
Chapter 4: Section 4: A o kọ Basic SQL ati Extract Transform Load fun Software Tester
Lecture 1: Bi a o ṣe Connecting Microsoft SQL Server Database pẹlu Management Studio
Lecture 2: Bi a o ṣe Migrate MS Access Database lo si MSSQL Server Database Engine
Lecture 3: Nipa SSIS Execution Result Errors (ETL Testing)
Lecture 4: A o kọ Database Testing nipa li lo Extract Transform Load (ETL) pt 1
Lecture 5: A o kọ Database Testing nipa li lo Extract Transform Load (ETL) pt 2
Lecture 6: A o kọ Database Testing nipa li lo Extract Transform Load (ETL) pt 3
Lecture 7: A o kọ Database Testing nipa li lo Extract Transform Load (ETL) pt 4
Lecture 8: A o kọ Database Testing nipa li lo Extract Transform Load (ETL) pt 5
Lecture 9: A o kọ nipa Data Testing Pẹ́lu MSSQL Server database
Chapter 5: Section 5: A o kọ Automation Trick ti Software Tester Le Lo
Lecture 1: A o kọ nipa Locating Web Elements Fun Selenium WebDriver
Lecture 2: A o kọ nipa Selenium WebDriver Web Element User Interactions
Lecture 3: A o kọ nipa Selenium WebDriver Test Design Techniques
Lecture 4: A o kọ nipa Selenium WebDriver Code Templates
Lecture 5: Bi a o ṣe lo (How To Use) Selenium WebDriver Code Templates
Lecture 6: A o kọ nipa What is iMacros
Lecture 7: A o kọ nipa lilo iMacros lati fi Record Web Browser
Lecture 8: A o kọ nipa lilo WinAutomation Software
Chapter 6: Section 6: A o kọ nipa Desktop Applications Testing
Lecture 1: Nipa Desktop Application Projects
Lecture 2: ***HOMEWORK – nipa AccessDB***
Lecture 3: ***HOMEWORK – nipa Afritelly Encoder v2016***
Lecture 4: ***HOMEWORK – nipa Afritelly Encoder v2017***
Lecture 5: ***HOMEWORK – nipa AllDB***
Lecture 6: ***HOMEWORK – nipa Colouring Book***
Lecture 7: ***HOMEWORK – nipa AfritellyDesigner***
Lecture 8: ***HOMEWORK – nipa DirectoryCleaner***
Lecture 9: ***HOMEWORK – nipa Afritelly Route Planner***
Lecture 10: ***HOMEWORK – nipa ProcessInfo***
Chapter 7: Section 7: A o kọ nipa Mobile Apps Testing
Lecture 1: Nipa Mobile Application Projects
Lecture 2: ***HOMEWORK – nipa iBarcode Scanner***
Lecture 3: ***HOMEWORK – nipa iComment***
Lecture 4: ***HOMEWORK – nipa iDeviceInfo***
Lecture 5: ***HOMEWORK – nipa iPictureUp***
Lecture 6: ***HOMEWORK – nipa iPlan***
Lecture 7: ***HOMEWORK – nipa iQuiz***
Lecture 8: ***HOMEWORK – nipa iSimple Barcode Scanner***
Chapter 8: Section 8: A o kọ nipa Web Applications Testing
Lecture 1: Nipa Web Application Projects
Lecture 2: ***HOMEWORK – nipa Simple Webshop***
Lecture 3: ***HOMEWORK – nipa Advanced Webshop***
Chapter 9: Section 9: A o kọ lati le Create Test Script Template
Lecture 1: A o kọ lati le Create Test Script Template pẹlu Microsoft Excel
Lecture 2: A o kọ lati le Embed MS Word Object inside Master Template
Chapter 10: Section 10: A o kọ lati le Create Test Scenario (Test Condition)
Lecture 1: ***IWE NIPA TEST CASES CHECKLISTs***
Lecture 2: Nipa Guide fun Creating Test Scenario
Chapter 11: Section 11: Nipa Working Experience
Lecture 1: Nipa Knowledge Acquired
Lecture 2: Join Online Testing Forum
Instructors
-
Ola Francis
IT Specialist|Test Analyst|BI Data Analyst|Big Data Engineer
Rating Distribution
- 1 stars: 1 votes
- 2 stars: 0 votes
- 3 stars: 3 votes
- 4 stars: 8 votes
- 5 stars: 20 votes
Frequently Asked Questions
How long do I have access to the course materials?
You can view and review the lecture materials indefinitely, like an on-demand channel.
Can I take my courses with me wherever I go?
Definitely! If you have an internet connection, courses on Udemy are available on any device at any time. If you don’t have an internet connection, some instructors also let their students download course lectures. That’s up to the instructor though, so make sure you get on their good side!
You may also like
- Top 10 Video Editing Courses to Learn in November 2024
- Top 10 Music Production Courses to Learn in November 2024
- Top 10 Animation Courses to Learn in November 2024
- Top 10 Digital Illustration Courses to Learn in November 2024
- Top 10 Renewable Energy Courses to Learn in November 2024
- Top 10 Sustainable Living Courses to Learn in November 2024
- Top 10 Ethical AI Courses to Learn in November 2024
- Top 10 Cybersecurity Fundamentals Courses to Learn in November 2024
- Top 10 Smart Home Technology Courses to Learn in November 2024
- Top 10 Holistic Health Courses to Learn in November 2024
- Top 10 Nutrition And Diet Planning Courses to Learn in November 2024
- Top 10 Yoga Instruction Courses to Learn in November 2024
- Top 10 Stress Management Courses to Learn in November 2024
- Top 10 Mindfulness Meditation Courses to Learn in November 2024
- Top 10 Life Coaching Courses to Learn in November 2024
- Top 10 Career Development Courses to Learn in November 2024
- Top 10 Relationship Building Courses to Learn in November 2024
- Top 10 Parenting Skills Courses to Learn in November 2024
- Top 10 Home Improvement Courses to Learn in November 2024
- Top 10 Gardening Courses to Learn in November 2024